Posts

Showing posts with the label Sola Allyson Songs

I Wonder (Lyrics) Leeland

Image
I Wonder (Lyrics) Leeland Mp4 YouTube Video Leeland -  I Wonder Lyrics  At the stars in the night, I wonder At Your lightning in the sky, I shudder Your glory is a blanket that covers Every living thing I’m in awe at the majesty of who You are Your love is a seal burnt inside my heart All of the day I want to be where You are Holy Father And it feels like there’s not enough praise inside of me With all these words, all my heart can sing is holy You are holy Jesus Christ You bled Your love, laid down Yourself And gave me life In naked shame You hung and You were lifted high Here I lay in awe and wonder I am afraid For no one’s ever sacrificed and loved me this way So on my face I fall under Your heavy grace Here I lay in awe and wonder And I wonder I’m in awe at the majesty of who You are Your love is a seal burnt inside my heart All of the day I want to be where You are Holy Father And it feels like there’s not enough praise inside of me With all these words, all my heart can ...

Agbonmagbe Lyrics Sola Allyson

Image
Agbonmagbe — Sola Allyson  (Lyrics)  YouTube Video    Sola Allyson — Agbonmagbe (Lyrics)   Chorus: Agbonmagbe ni ore latodo oluwa Resp: Agbonmagbe ni ore latodo oluwa Agbonmagbe ni ore latodo oluwa Resp: Agbonmagbe ni ore latodo oluwa Eni pase ore ti o le tan loluwa resp: Eni pase ore ti o le tan loluwa Nibo lore ti nwa bi osodo baba wa resp: Nibo lore ti nwa bi osodo baba wa Agbonmagbe ni ore latodo oluwa Resp: Agbonmagbe ni ore latodo oluwa Pro Chorus All: Agbamagbe lokun Agbomagbe losa Tori agbonmagbe ni baba to pase won Agbamagbe lokun Agbomagbe losa Tori agbonmagbe ni baba to pase won Verse: Baba Olore Baba Olore Baba Olore Baba Olore Ore ti ose salaye Ore tiokin tan odo re ni won ti nwa Baba agbo n gbe Koseni to dabi re Buso buso lore re talo le bi e lejo Abubu tan ni Olola ta le gba Olore ti o se daye le Mo paya re oloremi Ore ti ose diyele Iwo lo ni lowo Mopaya re olore agbon gbe Chorus: Agbonmagbe ni ore latodo oluwa Resp: Agbonmagbe ni ore latodo oluw...

Ijoba a Re De Lyrics Sola Allyson

Image
 Ijoba a Re De — Sola Allyson (Lyrics) YouTube Video   Sola Allyson — Ìjọba Rẹ Dé Lyrics Ijoba re de ase re bere Ijoba re de ase re bere Agbara wa oba sori mi Ijoba re de ase re bere Ijoba re de ase re bere Ijoba re de ase re bere Agbara wa oba sori mi Ijoba re de ase re bere call: ijoba re de resp: Ijoba re de ase re bere (Ijoba ola, Ijoba agbara, Ijoba alafia) Ijoba re de ase re bere Agbara wa oba sori mi Ijoba re de ase re bere Ijoba re de ase re bere Ijoba re de ase re bere Agbara wa oba sori mi Ijoba re de ase re bere Iranwo wa sori isedami Ijoba re de ase re bere (ijoba riri iranwo nitemi) Ijoba re de ase re bere Agbara wa oba sori mi Ijoba re de ase re bere Ogbemi wo bi aso Benani oro re losobe Mokele oro re Ijoba re de ase re bere Ijoba re de ase re bere Agbara wa oba sori mi Ijoba re de ase re bere Okunkun tan imole de iranwo de iranwo Gbogbo ise n gun mi lowo Okunkun tan imole de iranwo de iranwo Gbogbo ise n gun mi lowo Ijoba a Re De — Sola Allyson (Lyrics) is...

Ife A D’ale — Sola Allyson (Lyrics)

Image
 Ife A D’ale —  Sola Allyson (Lyrics)  YouTube Video Sola Allyson — Ife A D’ale ife wa adale ife wa adale Oooo ife wa adale ife wa adale ire ife wa adale ife wa adale Oooo Bena ni ife wa adale ife eyi adale ire Ire latoke wa Ibukun ti ki nsi lo Ire ti kin  gbo danu Ife eyi adale o Ire latoke wa Ibukun ti ki nsi lo Ire ti kin  gbo danu Ife eyi adale o ife wa adale ife wa adale Oooo ife wa adale ife wa adale ire ( ao ni subu) ife wa adale ife wa adale Oooo Bena ni ife wa adale ife eyi adale ire Ire latoke wa Ibukun ti ki nsi lo Ire ti kin  gbo danu Ife eyi adale o Ire latoke wa Ibukun ti ki nsi lo Ire ti kin  gbo danu Ife eyi adale o ife wa adale ife wa adale ( oju oni ti wa lailai ) Oooo ife wa adale ife wa adale ire (ododun loa n rorogbo) ife wa adale ife wa adale Oooo Bena ni ife wa adale ife eyi adale ire Iranwo awa fun wa Ojurere at alanu iranwao awa fun wa Agbara lowo eldumare adwa mu idimu adiwa mu o Ao ri ike ati ige lona wa Ike ati ige amaba wa ...