Iba F’alade Ogo - Song Lyrics by OBA
- Get link
- X
- Other Apps
Iba F’alade Ogo - Song Lyrics by OBA
Lyrics for Iba F’alade Ogo by OBA
Moriba moriba babami
Eledumare Oba awon oba
Feledumare
Iba F’Feledumare
Feledumare
Oba to laye ati orun
Feledumare
Aiku aisa aidibaje
Feledumare
Mojuba Olorun to ngbe nu mimo
Ogo nifun baba atomo
Ati emi mimo
Ogo nifun baba atomo
Ati emi mimo
Ogo nifun baba atomo
Ati emi mimo
Ogo nifun baba atomo
Feledumare
Iba ’Feledumare
Feledumare
Oba to laye ati orun
Feledumare
Aiku aisa aidibaje
Feledumare
Emi ni tin je emi ni Olorun alaye
Feledumare
Iba F’alade Ogo
Eledumare Awimayehun
Iba F’alade Ogo
Eledumare Awimayehun
Iba F’alade Ogo
Eledumare Awimayehun (mori mori ti nmori awon eniyan)
Iba F’alade Ogo
Eledumare Awimayehun
Iba F’alade Ogo
Eledumare Awimayehun (all the Glory belongs to You)
Iba F’alade Ogo
Eledumare Awimayehun (iba Feledami)
Iba F’alade Ogo
Eledumare Awimayehun (Begining and the end)
Iba F’alade Ogo
Eledumare Awimayehun
Yagbo yaju okunrin Ogun
Ogo The angels Crying
Blessing and Honour Ogo Ogo
Ogo
- Get link
- X
- Other Apps
Comments
Post a Comment